Psalms 88:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo dàbí àwọn tí ó ń wọ ibojì lọ; mo dà bí ẹni tí kò lágbára mọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kà mi pẹlu kún awọn ti o sọkalẹ lọ si ihò: emi dabi ọkunrin ti kò ni ipá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A kà mí mọ́ àwọn tí wọ́n lọ sí ọ̀gbun ilẹ̀ èmi dà bí ọkùnrin tí kò ni agbára.