Psalms 88:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O ti mú kí àwọn ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi fi mí sílẹ̀; mo sì ti di ẹni ìríra lọ́dọ̀ wọn: mo wà ninu àhámọ́, n kò sì lè jáde;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti mu awọn ojulumọ mi jina si mi; iwọ si sọ mi di irira si wọn; a se mi mọ́, emi kò le jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ tí gba ọ̀rẹ́ mi tí ó súnmọ́ mí kúrò lọ́wọ́ mi ìwọ sì sọ mi di ìríra sí wọn. A há mi mọ́, èmi kò sì lé è jáde;