Psalms 89:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Tìrẹ ni ọ̀run, tìrẹ sì ni ayé pẹlu; ìwọ ni o tẹ ayé ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ dó.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrun ni tirẹ, aiye pẹlu ni tirẹ: aiye ati ẹ̀kun rẹ̀, iwọ li o ti ṣe ipilẹ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tìrẹ ní àwọn ọ̀run, ayé pẹ̀lú jẹ tìrẹ: ayé àti ohun gbogbo tí ó wà nínú Rẹ̀: ìwọ ti gbé wọn kalẹ̀.