Psalms 89:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ó mọ ìhó ayọ̀ nnì, àwọn tí ń rìn ninu ìmọ́lẹ̀ ojurere rẹ, OLUWA,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún ni fun awọn enia ti o mọ̀ ohùn ayọ̀ nì: Oluwa, nwọn o ma rìn ni imọlẹ oju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ní fún àwọn ènìyàn tí wọn mọ igbe ayọ̀, tí ó ń rìn OLÚWA nínú ìmọ́lẹ̀ oju Rẹ.