Psalms 89:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
àwọn tí ń yọ̀ nítorí orúkọ rẹ tọ̀sán-tòru, tí sì ń gbé òdodo rẹ lárugẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li orukọ rẹ ni nwọn o ma yọ̀ li ọjọ gbogbo: ati ninu ododo rẹ li a o ma gbé wọn leke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn ń ṣògo nínú orúkọ Rẹ̀ ní gbogbo ọjọ́, wọn ń yin òdodo Rẹ.