bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 89:17
Psalms 89:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ìwọ ni ògo ati agbára wọn; nípa ojurere rẹ sì ni a ti ní ìṣẹ́gun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ li ogo agbara wọn: ati ninu ore ojurere rẹ li a o gbé iwo wa soke,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ìwọ ni ògo agbára wọn; nípa ojúrere ni ìwọ wá ń ṣògo.