Psalms 89:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ìgbàanì, o sọ ninu ìran fún olùfọkànsìn rẹ pé, “Mo ti fi adé dé alágbára kan lórí, mo ti gbé ẹnìkan ga tí a yàn láàrin àwọn eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni iwọ sọ li oju iran fun ayanfẹ rẹ, o si wipe, Emi ti gbé iranlọwọ ru ẹni-alagbara; emi ti gbé ẹnikan leke ti a yàn ninu awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ní ìwọ sọ̀rọ̀ nínú ìran sí àwọn olótítọ́ Rẹ, wí pé: “èmi tí gbé adé kálẹ̀ sórí ẹni tí ó lágbára, èmi ti gbé ẹni tí a yan láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn ga.