Psalms 89:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
n óo nà wọ́n lẹ́gba nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn, n óo sì nà wọ́n ní pàṣán nítorí àìdára wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li emi o fi ọgọ bẹ irekọja wọn wò, ati ẹ̀ṣẹ wọn pẹlu ìna.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni èmi o fì ọ̀gà bẹ irékọjá wọn wò àti ẹ̀ṣẹ̀ wọn pẹ̀lú ìná: