Psalms 89:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
‘N óo fi ìdí àwọn ọmọ rẹ múlẹ̀ títí lae, n óo sì gbé ìtẹ́ rẹ ró láti ìran dé ìran.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Irú-ọmọ rẹ li emi o gbé kalẹ lailai, emi o si ma gbé itẹ́ rẹ ró lati irandiran,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ó fi ìdí irú ọmọ Rẹ múlẹ̀ títí láé èmí ó sì máa gbe ìtẹ́ Rẹ ró láti ìran dé ìran”.