Psalms 89:47 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, ranti bí ọjọ́ ayé ẹ̀dá ti gùn mọ, ati pé ẹ̀dá lásán ni ọmọ eniyan!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ranti bi ọjọ mi ti kuru to; ẽse ti iwọ ha da gbogbo enia lasan?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rántí bí ọjọ́ mi ti kúrú tó nítorí asán ha ní ìwọ fi sẹ̀dá àwọn ènìyàn!