Psalms 89:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí ojú ọ̀run máa kọrin ìyìn iṣẹ́ ìyanu rẹ, OLÚWA; kí àwọn eniyan mímọ́ sì máa kọrin ìyìn òtítọ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrun yio si ma yìn iṣẹ-iyanu rẹ, Oluwa, otitọ rẹ pẹlu ninu ijọ enia mimọ́ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀run yóò mú yín ṣiṣẹ́ ìyanu Rẹ, OLÚWA, òtítọ́ Rẹ ní ìpéjọpọ̀ àwọn ẹni mímọ́.