Psalms 89:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ta ni a lè fi wé ọ ní ọ̀run, OLUWA? Ta ni ó dàbí OLUWA láàrin àwọn ẹ̀dá ọ̀run?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe, tali o wà li ọrun ti a le fi wé Oluwa? tani ninu awọn ọmọ alagbara, ti a le fi wé Oluwa?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ta ní ó wà ni ọ̀run ti a lè fi we OLÚWA? Ta ni nínú àwọn ọmọ alágbára ti a lè fi wé OLÚWA?