Psalms 89:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ò ń jọba lórí òkun tí ń ru; nígbà tí ìgbì rẹ̀ bá ru sókè, ìwọ ni ò ń mú kí ó rọlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ li o jọba ibinu okun; nigbati riru omi rẹ̀ dide, iwọ mu u pa rọrọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ń darí ríru omi òkun; nígbà tí ó ru àwọn omi sókè, ìwọ mú wọn pa rọ́rọ́.