Psalms 9:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ kọrin ìyìn sí OLUWA, tí ó gúnwà ní Sioni! Ẹ kéde iṣẹ́ rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ kọrin iyìn si Oluwa, ti o joko ni Sioni: ẹ fi iṣẹ rẹ̀ hàn ninu awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kọ orin ìyìn sí OLÚWA, ti o ń jọba ní Síónì; kéde láàrin àwọn orílẹ̀ èdè ohun tí o ṣe.