Psalms 9:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
kí n lè kọrin ìyìn rẹ, kí n sì lè yọ ayọ̀ ìgbàlà rẹ lẹ́nu ibodè Sioni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki emi ki o le ma fi gbogbo iyìn rẹ hàn li ẹnu-ọ̀na ọmọbinrin Sioni, emi o ma yọ̀ ni igbala rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí èmi kí o lè sọ ti ìyìn Rẹ ni ẹnu ọ̀nà àwọn ọmọbìnrin Síónì àti láti máa yọ̀ nínú ìgbàlà Rẹ.