Psalms 9:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀-èdè ti jìn sinu kòtò tí wọ́n gbẹ́, wọ́n sì ti kó sinu àwọ̀n tí wọ́n dẹ sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn orilẹ-ède jìn sinu ọ̀fin ti nwọn wà: ninu àwọn ti nwọn dẹ silẹ li ẹsẹ ara wọn kọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè ti jìn sí kòtò ti wọn ti gbẹ́; ẹsẹ̀ wọn ni àwọ̀n tí wọ́n dẹ sílẹ̀ kọ́.