Psalms 9:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn eniyan burúkú, àní, gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó gbàgbé Ọlọrun, ni yóo lọ sinu isà òkú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ori awọn enia buburu li a o dà si ọrun apadi, ati gbogbo orilẹ-ède ti o gbagbe Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ènìyàn búburú ni a ó dà sí isà òkú, àti gbogbo orílẹ̀ èdè tí ó gbàgbé Ọlọ́run.