Psalms 9:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí pé OLUWA kò ní fi ìgbà gbogbo gbàgbé àwọn aláìní, bẹ́ẹ̀ ni ìrètí àwọn talaka kò ní já sí òfo títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe a kì yio gbagbe awọn alaini lailai: abá awọn talaka kì yio ṣegbe lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àwọn aláìní ni a ò ní gbàgbé láéláé, ìrètí àwọn ti ó talakà lójú kí yóò ṣègbé láéláé.