Psalms 9:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, da ẹ̀rùjẹ̀jẹ̀ bò wọ́n, jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ pé aláìlágbára eniyan ni àwọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dẹru ba wọn, Oluwa: ki awọn orilẹ-ède ki o le mọ̀ ara wọn pe, enia ṣa ni nwọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lù wọ́n pẹ̀lú ìpayà, OLÚWA; jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè mọ̀ pé ènìyàn lásán ni wọ́n. Sela