Psalms 9:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà tí àwọn ọ̀tá mi pẹ̀yìndà, wọ́n ṣubú, wọ́n sì parun níwájú rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn ọta mi ba pẹhinda, nwọn o ṣubu, nwọn o si ṣegbe ni iwaju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀ta mi pẹ̀yìndà; Wọ́n kọsẹ̀ wọn sì ṣègbé níwájú Rẹ.