Psalms 9:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O pa àwọn ọ̀tá run patapata, o sọ ìlú wọn di ahoro, o sì sọ wọ́n di ẹni ìgbàgbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Niti ọta, iparun wọn pari tan lailai: iwọ li o si ti run ilu wọnni; iranti wọn si ti ṣegbe pẹlu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìparun àìlópin ti borí àwọn ọ̀ta, Ìwọ ti fa àwọn ìlú wọn tu; Àní ìrántí wọn sì ti sègbé.