Psalms 90:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aadọrin ọdún ni ọjọ́ ayé wa; pẹlu ipá a lè tó ọgọrin; sibẹ gbogbo rẹ̀ jẹ́ kìkì làálàá ati ìyọnu; kíá, ayé wa á ti dópin, ẹ̀mí wa á sì fò lọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Adọrin ọdun ni iye ọjọ ọdun wa; bi o si ṣepe nipa ti agbara, bi nwọn ba to ọgọrin ọdun, agbara wọn lãla on ibinujẹ ni; nitori pe a kì o pẹ ke e kuro, awa a si fò lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àádọ́rin ọdún ni iye ọjọ́ ọdún: wá, tí ó sì ṣe pé nipa agbára tí wọn bá tó ọgọrìn ọdún agbára wọn làálàá pẹ̀lú ìbànújẹ́ ni nítorí pé a kò ni gé e kúrò, àwa a sì fò lọ.