Psalms 90:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà kọ́ wa láti máa ka iye ọjọ́ orí wa, kí á lè kọ́gbọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni ki iwọ ki o kọ́ wa lati ma ka iye ọjọ wa, ki awa ki o le fi ọkàn wa sipa ọgbọ́n.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kọ́ wa bí a ti ń kàye ọjọ́ wa dáradára, kí àwa bá a le fi ọkàn wa sípa ọgbọ́n.