Psalms 90:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí iṣẹ́ rẹ hàn sí àwọn iranṣẹ rẹ, kí agbára rẹ tí ó lógo sì hàn sí àwọn ọmọ wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki iṣẹ rẹ ki o hàn si awọn ọmọ-ọ̀dọ rẹ, ati ogo rẹ si awọn ọmọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí a fi iṣẹ́ Rẹ̀ hàn àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ Rẹ̀, ògo Rẹ̀ sì àwọn ọmọ wọn.