Psalms 90:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìwọ a máa gbá ọmọ eniyan dànù; wọ́n dàbí àlá, bíi koríko tí ó tutù ní òwúrọ̀;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ kó wọn lọ bi ẹnipe ni ṣiṣan-omi; nwọn dabi orun; ni kutukutu nwọn dabi koriko ti o dagba soke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ gbá ènìyàn dánù nínú oorun ikú; wọ́n dàbí koríko tuntun ní òwúrọ̀.