Psalms 90:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ọjọ́ ayé wa ń kọjá lọ ninu ibinu rẹ; ayé wa sì ń dópin bí ẹni mí kanlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ọjọ wa gbogbo nyipo lọ ninu ibinu rẹ: awa nlo ọjọ wa bi alá ti a nrọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ọjọ́ wa ń kọjá lọ lábẹ́ ìbínú Rẹ; àwa n lo ọjọ wá lọ bí àlá ti a ń rọ́.