Psalms 91:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí yóo pàṣẹ fún àwọn angẹli rẹ̀, nítorí rẹ, pé kí wọ́n máa pa ọ́ mọ́ ní gbogbo ọ̀nà rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti yio fi aṣẹ fun awọn angeli rẹ̀ nitori rẹ, lati pa ọ mọ́ li ọ̀na rẹ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí yóò fi àṣẹ fún àwọn ańgẹ́lì nípa tìrẹ láti pa ọ́ mọ ní gbogbo ọ̀nà Rẹ;