Psalms 91:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí yóo yọ ọ́ ninu okùn àwọn pẹyẹpẹyẹ ati ninu àjàkálẹ̀ àrùn apanirun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitõtọ on o gbà ọ ninu ikẹkun awọn pẹyẹpẹyẹ, ati ninu àjakalẹ-àrun buburu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní tòótọ́ òun yóò gbà mí nínú ìdẹkùn àwọn pẹyẹ pẹyẹ àti nínú àjàkálẹ̀-àrùn búburú.