Psalms 92:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọn á máa so èso títí di ọjọ́ ogbó wọn, wọn á máa lómi lára, ewé wọn á sì máa tutù nígbà gbogbo;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o ma so eso sibẹ ninu ogbó wọn: nwọn o sanra, nwọn o ma tutù nini;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn yóò máa so èso ní ìgbà ogbó wọn yóò dúró ní àkọ̀tun, wọn yóò sì tutù nini,