Psalms 92:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
pé bí eniyan burúkú bá tilẹ̀ rú bíi koríko, tí gbogbo àwọn aṣebi sì ń gbilẹ̀, ó dájú pé ìparun ayérayé ni òpin wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn enia buburu ba rú bi koriko, ati igbati gbogbo awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ ba ngberú: ki nwọn ki o le run lailai ni:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àwọn ènìyàn búburú bá rú jáde bí i koríko àti gbogbo àwọn olùṣe búburú gbèrú, wọn yóò run láéláé.