Psalms 92:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wò ó, OLUWA, àwọn ọ̀tá rẹ yóo parun; gbogbo àwọn aṣebi yóo sì fọ́n ká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sa wò o, awọn ọta rẹ, Oluwa, sa wò o, awọn ọta rẹ yio ṣegbe; gbogbo oniṣẹ ẹ̀ṣẹ li a o tuka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí nítòótọ́ àwọn ọ̀tá Rẹ, OLÚWA, nítòótọ́ àwọn ọ̀ta Rẹ yóò ṣègbé; gbogbo àwọn olùṣe búburú ní a ó fọ́nká.