Psalms 94:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún ẹni tí o bá báwí, OLUWA, tí o sì kọ́ ní òfin rẹ,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibukún ni fun enia na ẹniti iwọ nà, Oluwa, ti iwọ si kọ́ lati inu ofin rẹ wá;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ni fún ènìyàn náà tí ìwọ báwí, OLÚWA, ẹni tí ìwọ kọ́ nínú òfin Rẹ;