Psalms 94:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
nítorí pé ìdájọ́ òtítọ́ yóo pada jẹ́ ìpín àwọn olódodo, àwọn olóòótọ́ yóo sì máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn idajọ yio pada si ododo: gbogbo ọlọkàn diduro ni yio si ma tọ̀ ọ lẹhin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìdájọ́ yóò padà sí òdodo, àti gbogbo àwọn ọlọ́kàn dídúró ṣinṣin yóò tẹ̀ lé e lẹ́yìn.