bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 94:21
Psalms 94:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n para pọ̀ láti gba ẹ̀mí olódodo; wọ́n sì dá ẹjọ́ ikú fún aláìṣẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn kó ara wọn jọ pọ̀ si ọkàn olododo, nwọn si da ẹ̀jẹ alaiṣẹ lẹbi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n kó ara wọn jọ si olódodo wọ́n sì ń dá àwọn aláìsẹ̀ lẹ́bi sí ikú.