Psalms 94:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Yóo san ẹ̀san ẹ̀ṣẹ̀ wọn fún wọn, yóo pa wọ́n run nítorí ìwà ìkà wọn. OLUWA Ọlọrun wa yóo pa wọ́n run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
On o si mu ẹ̀ṣẹ wọn bọ̀ sori ara wọn, yio si ke wọn kuro ninu ìwa-buburu wọn: Oluwa Ọlọrun wa, yio ke wọn kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òun yóò san ẹ̀san ibi wọn fún wọn yóò sì pa wọ́n run nítorí búburú wọn OLÚWA Ọlọ́run wa yóò pa wọ́n run.