Psalms 94:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n ń fi ìgbéraga sọ̀rọ̀ jàbùjàbù, gbogbo àwọn aṣebi ní ń fọ́nnu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn o ti ma dà ọ̀rọ nù ti nwọn o ma sọ ohun lile pẹ to? ti gbogbo oniṣẹ ẹ̀ṣẹ yio fi ma fi ara wọn leri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n ń sọ̀rọ̀ ìgbérága jáde; gbogbo àwọn olùṣebúburú kún fún ìṣògo.