Psalms 94:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ jẹ́ kí ó ye yín, ẹ̀yin tí ẹ ya òpè jùlọ láàrin àwọn eniyan! Ẹ̀yin òmùgọ̀, nígbà wo ni ẹ óo gbọ́n?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki oye ki o ye nyin, ẹnyin ope ninu awọn enia: ati ẹnyin aṣiwere, nigbawo li ẹnyin o gbọ́n?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí i, ẹ̀yin aláìlóye nínú àwọn ènìyàn ẹ̀yin aṣiwèrè, nígbà wo ni ẹ̀yin yóò lóye?