Psalms 95:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nígbà tí àwọn baba ńlá yín dán mi wò, tí wọ́n dẹ mí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti rí ohun tí mo ti ṣe rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati awọn baba nyin dan mi wò, ti nwọn wadi mi, ti nwọn si ri iṣẹ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà ti àwọn baba yin dán mi wò ti wọn wádìí mi, ti wọn sì ri iṣẹ́ mi