Psalms 96:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí inú ọ̀run ó dùn, sì jẹ́ kí ayé ó yọ̀; kí òkun ó hó, ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki ọrun ki o yọ̀, jẹ ki inu aiye ki o dùn; jẹ ki okun ki o ma ho pẹlu ikún rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí àwọn ọ̀run kí ó yọ̀, kí ayé sì dùn jẹ́ kí òkun kí ó hó pẹ̀lú ohun gbogbo tí ń bẹ nínú Rẹ̀.