Psalms 96:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Jẹ́ kí pápá oko ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀ yọ̀. Nígbà náà ni gbogbo igi igbó yóo fi ayọ̀ kọrin,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki oko ki o kún fun ayọ̀, ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu rẹ̀: nigbana ni gbogbo igi igbo yio ma yọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí oko kún fún ayọ̀ àti ohun gbogbo ti ń bẹ nínú Rẹ̀: nígbà náà ni gbogbo igi igbó yóò máa yọ̀