Psalms 96:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ kéde ògo rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè; ẹ sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sọ̀rọ ogo rẹ̀ lãrin awọn keferi, ati iṣẹ iyanu rẹ̀ lãrin gbogbo enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ sọ ti ògo Rẹ̀ láàrin àwọn orílẹ̀ èdè àti iṣẹ́ ìyanu Rẹ̀ láàrin gbogbo ènìyàn.