Psalms 96:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí oriṣa lásán ni àwọn orílẹ̀-èdè yòókù ń sìn, ṣugbọn OLUWA ni ó dá ọ̀run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori pe gbogbo oriṣa orilẹ-ède asan ni nwọn: ṣugbọn Oluwa li o da ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí aṣán ni gbogbo àwọn òrìsà orílẹ̀ èdè ṣùgbọ́n OLÚWA dá àwọn ọ̀run