Psalms 97:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ojú ti gbogbo àwọn tí ń bọ oriṣa, àwọn tí ń fi ère lásánlàsàn yangàn; gbogbo oriṣa ní ń foríbalẹ̀ níwájú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju yio tì gbogbo awọn ti nsìn ere fifin, ẹniti nfi ere ṣe ileri ara wọn: ẹ ma sìn i, gbogbo ẹnyin ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn tí ń sin òrìṣà ni ojú yóò ti, àwọn ti n fi ère ṣe àfẹ́rí ara wọn Ẹsìn ín, ẹ̀yin òrìṣà;