Psalms 97:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Sioni gbọ́, inú wọn dùn. Àwọn ará ìlú Juda sì ń yọ̀, nítorí ìdájọ́ rẹ, OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sioni gbọ́, inu rẹ̀ si dùn; awọn ọmọbinrin Juda si yọ̀, Oluwa, nitori idajọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Síónì gbọ́, inú Rẹ̀ sì dùn ìnú àwọn ilé Júdà sì dùn Nítorí ìdájọ́ Rẹ, OLÚWA