Psalms 98:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí òkun ó hó, ati gbogbo ohun tí ó wà ninu rẹ̀, kí ayé hó, ati àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki okun ki o ma ho pẹlu ikún rẹ̀; aiye, ati awọn ti mbẹ ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí òkun kí o hó pẹ̀lú gbogbo ohun tí ó wà nínú Rẹ̀, Gbogbo ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú Rẹ̀.