Psalms 99:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mose ati Aaroni wà lára àwọn alufaa rẹ̀; Samuẹli pàápàá wà lára àwọn tí ń pe orúkọ rẹ̀; wọ́n ké pe OLUWA ó sì dá wọn lóhùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mose ati Aaroni ninu awọn alufa rẹ̀, ati Samueli ninu awọn ti npè orukọ rẹ̀: nwọn ke pè Oluwa, o si da wọn lohùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mósè àti Árónì wà nínú àwọn àlùfáà Rẹ̀ Sámúẹ́lì wà nínú àwọn tí ó ń ké pe orúkọ Rẹ̀ wọ́n képe OLÚWA, ó sì dá wọn lóhùn.