Revelation 10:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n bá sọ fún mi pé, “O níláti tún kéde fún ọ̀pọ̀ àwọn eniyan ati oríṣìíríṣìí ẹ̀yà ati àwọn orílẹ̀-èdè, ati ọpọlọpọ ìjọba.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A si wi fun mi pe, Iwọ o tún sọ asọtẹlẹ lori ọpọlọpọ enia, ati orilẹ, ati ède, ati awọn ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A sì wí fún mi pé, “Ìwọ ó sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ènìyàn, àti orílẹ̀ àti èdè, àti àwọn ọba.”