Revelation 17:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ète kanṣoṣo ni wọ́n ní. Wọn yóo fi agbára wọn ati àṣẹ wọn fún ẹranko náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn wọnyi ni inu kan, nwọn o si fi agbara ati ọla wọn fun ẹranko na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wọ̀nyí ní inú kan, wọ́n ò sì fi agbára àti ọlá wọn fún ẹranko náà.