Revelation 18:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn oníṣòwò ayé yóo sunkún, wọn yóo ṣọ̀fọ̀ lé e lórí, nítorí wọn kò rí ẹni ra ọjà wọn mọ́; àwọn nǹkan bíi:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn oniṣowo aiye si nsọkun, nwọn si nṣọ̀fọ lori rẹ̀; nitoripe ẹnikẹni kò rà ọjà wọn mọ́:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àwọn oníṣòwò ayé sì ń sọkún, wọn sì ń sọ̀fọ̀ lórí rẹ̀, nítorí pé ẹnikẹ́ni kò rà ọjà wọn mọ́: