Revelation 18:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọba ayé ati àwọn tí wọ́n ti bá a ṣe àgbèrè, tí wọ́n ti ń bá a jayé yóo sunkún, wọn óo ṣọ̀fọ̀ lé e lórí nígbà tí wọ́n bá rí èéfín iná tí ń jó o.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ọba aiye, ti o ti mba a ṣe àgbere, ti nwọn si mba a hu iwà wọbia, yio si pohùnrere ẹkún le e lori, nigbati nwọn ba wo ẹ̃fin ijona rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Àti àwọn ọba ayé, tí ó ti ń bá a ṣe àgbérè, ti wọn sì ń hùwà wọ̀bìà, yóò sì pohùnréré ẹkún lé e lórí, nígbà tí wọn bá wo èéfín ìjóná rẹ̀.